Font Size
Luku 1:73
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Luku 1:73
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
73 ìbúra tí ó ti bú fún Abrahamu baba wa,
Heberu 6:13
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Heberu 6:13
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Ìdánilójú ìlérí Ọlọ́run
13 (A)Nítorí nígbà tí Ọlọ́run ṣe ìlérí fún Abrahamu, bí kò ti rí ẹni tí ó pọ̀jù òun láti fi búra, ó fi ara rẹ̀ búra, wí pé,
Read full chapter
Heberu 6:14
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Heberu 6:14
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
14 “Nítòótọ́ ní bíbùkún èmi ó bùkún fún ọ, àti ní bíbísí èmi ó sì mú ọ bí sí i.”
Read full chapter
Heberu 11:12
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Heberu 11:12
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
12 (A)Nítorí náà ni ọ̀pọ̀lọpọ̀ ṣe ti ara ọkùnrin kan jáde, àní ara ẹni tí o dàbí òkú, ọmọ bí ìràwọ̀ ojú ọ̀run lọ́pọ̀lọpọ̀, àti bí iyanrìn etí Òkun láìníye.
Read full chapter
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn (BYO)
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.