Font Size
Ìfihàn 4:9
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Ìfihàn 4:9
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
9 (A)Nígbà tí àwọn ẹ̀dá alààyè náà bá sì fi ògo àti ọlá, àti ọpẹ́ fún ẹni tí o jókòó lórí ìtẹ́, tí o ń bẹ láààyè láé àti láéláé.
Read full chapter
Ìfihàn 10:5
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Ìfihàn 10:5
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
5 (A)Angẹli náà tí mo rí tí ó dúró lórí Òkun àti lórí ilẹ̀, sì gbé ọwọ́ rẹ̀ sí òkè ọ̀run:
Read full chapter
Ìfihàn 12:14
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Ìfihàn 12:14
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
14 (A)A sì fi apá ìyẹ́ méjì tí idì ńlá náà fún obìnrin náà, pé kí ó fò lọ sí aginjù, sí ipò rẹ̀, níbi tí a ó gbe bọ ọ fún àkókò kan àti fún àwọn àkókò, àti fún ìdajì àkókò kúrò lọ́dọ̀ ejò náà.
Read full chapter
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn (BYO)
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.