Font Size
Gẹnẹsisi 25:9
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Gẹnẹsisi 25:9
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
9 (A)Àwọn ọmọ rẹ̀, Isaaki àti Iṣmaeli sì sin ín sínú ihò àpáta ni Makpela ní ẹ̀gbẹ́ Mamre, ní oko Efroni ọmọ Sohari ará Hiti
Read full chapter
Gẹnẹsisi 25:10
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Gẹnẹsisi 25:10
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
10 Inú oko tí Abrahamu rà lọ́wọ́ ara Hiti yìí ni a sin Abrahamu àti Sara aya rẹ̀ sí.
Read full chapter
Gẹnẹsisi 35:29
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Gẹnẹsisi 35:29
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
29 Isaaki sì kú láìpẹ́ lẹ́yìn ìpadàbọ̀ Jakọbu, a sì sin ín pẹ̀lú àwọn ènìyàn rẹ̀ ní ọjọ́ ogbó rẹ̀. Esau àti Jakọbu ọmọ rẹ̀ sì sin ín.
Read full chapter
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn (BYO)
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.