Font Size
Matiu 3:10
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Matiu 3:10
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
10 (A)Nísinsin yìí, a ti fi àáké lè gbòǹgbò igi, àti pé gbogbo igi tí kò bá so èso rere ni a óò ge lulẹ̀ ti a ó sì wọ jù sínú iná.
Read full chapter
Matiu 7:19
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Matiu 7:19
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
19 Gbogbo igi tí kò bá so èso rere, a gé e lulẹ̀, à wọ́ ọ jù sínú iná,
Read full chapter
Luku 3:9
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Luku 3:9
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
9 (A)Àti nísinsin yìí pẹ̀lú, a fi àáké lé gbòǹgbò igi náà: gbogbo igi tí kò bá so èso rere, a óò ge lulẹ̀, a sì wọ jù sínú iná.”
Read full chapter
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn (BYO)
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.