Font Size
1 Kọrinti 9:22
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
1 Kọrinti 9:22
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
22 (A)Nígbà tí mo bá wà láàrín àwọn aláìlera, èmi náà yóò di aláìlera, kí èmi lé jèrè àwọn aláìlera. Mo di ohun gbogbo fún gbogbo ènìyàn, kí èmi ba à lè gba díẹ̀ là lábẹ́ bí ó ti wù kí ó rí.
Read full chapter
Romu 15:2
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Romu 15:2
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
2 Olúkúlùkù wa gbọdọ̀ máa ṣe ohun tí ó wu ọmọnìkejì rẹ̀ sí rere, láti gbé e ró.
Read full chapter
1 Kọrinti 13:5
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
1 Kọrinti 13:5
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
5 (A)Ìfẹ́ kì í hùwà àìtọ́, kì í wá ohun ara rẹ̀ nìkan. Ìfẹ́ kì í bínú fùfù, ìfẹ́ kì í fi búburú ọmọ ẹnìkejì sínú.
Read full chapter
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn (BYO)
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.